Monday, May 4, 2020

NINU GBOGBO EWU ORU


 1. Ninu gbogbo ewu oru,
 Oluwa l’ o so mi;
 Awa si tun ri ’mole yi
 A tun te ekun ba.
 
2. Oluwa, pa wa mo l’ oni,
 Fi apa Re so wa;
 Kiki awon ti ’wo pamo,
 L’ o nyo ninu ewu.
 
 3. K’ oro wa, ati iwa wa
 Wipe, Tire l’ awa;
 Tobe t’ imole otito
 Le tan l’ oju aiye.
 
4. Ma je k’ a pada lodo Re,
 Olugbala owon:
 Titi a o f’ oju wa ri
 Oju Re li opin. Amin. 


No comments:

Post a Comment

ONWARD CHRISTIAN SOLDIERS

E-major 1: Onward, Christian soldiers, marching as to war, With the cross of Jesus going on before. Christ, the royal Master, leads against...