Saturday, May 2, 2020

FI IBUKUN RE TU WA KA

FI IBUKUN RE TU WA KA

FI ibukun Re tu wa ka,
Fi ayo kun okan wa;
K' olukuluku mo 'fe Re,
K' a l' ayo n' nu ore Re,
Tu wa lara, tu wa lara
La aginju aiye ja.

Ope at' iyin l 'a nfun O,
Fun ihinrere ayo;
Je ki eso igbala Re;
Po l'okan at' iwa wa;
Ki oju Re, ki oju Re
Ma ba wa gbe titi lo.

Nje, nigbat'a ba sip e wa
Lati f' aiye yi sile,
K' Angeli gbe wa lo s' orun,
L' ayo ni k'a jipe na;
K' a si joba, k' a si joba
Pelu Kristi titi lai.

No comments:

Post a Comment

ONWARD CHRISTIAN SOLDIERS

E-major 1: Onward, Christian soldiers, marching as to war, With the cross of Jesus going on before. Christ, the royal Master, leads against...